All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Monday, 2 July 2018




contact me if you need any of the above work and also the complete book is up for sale with full and detail description on how to use and go about it at an affordable price


Friday, 13 October 2017

ASINA TON CONNECT EYAN



Ao wa ako alangba kan ao pa ao ki owo dollar si lenu ao fi sinu ape ao fi atare odidi kan si legbe ao wada eso iwerenjeje le.lori aojo ao mafi schnap loo laro laro..pelu ase olohun  ao gba owo ao si connect mon eyan gidi

Monday, 24 July 2017

Ogun Airi Omo Bi



Ewe iyalode pupa
ewe mafowokan omomi
ewe akintola pupo…
leyin ao wa lo si bi ti igbo ba posi lowo otun ati osi
yi o di ju ja ewe otun pelu owo otun 
yi o di ju ja ewe osi pelu owo osi
ao wa fi gun po mo ose
… Ale ojo ti oba fi we o gbudo ni kan po pelu oko re.

Monday, 12 December 2016

Awure owo


Egbo iroko, egbo ipon, karagba idi esu, ose dudu, ao gun gbogbo re po, ao ma fi we lararo.,
gbolohun: “ipon loni kan pinre temi fun mi loni, iroko loni afaro.