All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Monday, 12 December 2016

Awure owo


Egbo iroko, egbo ipon, karagba idi esu, ose dudu, ao gun gbogbo re po, ao ma fi we lararo.,
gbolohun: “ipon loni kan pinre temi fun mi loni, iroko loni afaro.

2 comments:

  1. Ewe ama je o
    baba ejo e pari ofo yen

    ReplyDelete
  2. Please baba ewe ama je oooo ejowo epari ofo yen

    ReplyDelete