OGUN GBETUGBETU
ori ati iru ejo, esunsun ati iye re, ao Jo
gbogbo re po, ao fi oje bomubomu po si ni ikobere, fi senu ma soro
OFO RE--bi ejo ba fori ku ajo were, esunsun ki roju ati aso
re tore ojo ti a ba be bomubomu ni soje ma gbo temi......... Ao wa so ohun ti
aba Fe Beni yio ri
No comments:
Post a Comment