All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Tuesday, 8 November 2016

OLUGBOHUN TODAJU

odidi oga aiye, kenken tiwon fiwe oku, egbo
akerejupon, omi iwe oku. Ao gun kenken mo
egbo akerejupon ao po mose ao fi omi iwe po ose na,ao ko si enu oga aiye na, ao wa bomole fun bi 1hrs, oga na yio tiku, ao fi igi ko ose na jade lenu oga na, aogbodo fi owo ko ose na ooo, ao ko sinu iwo etu, ao fi aso waji bo ose na, ao wa fi aso pupa bo lori! Ao da epo pupa lori Olugbohun yi, ao gbe pamo sinu odo fun ojo meje, ao gbodo fi ahon kan olugbohun yi, ao ma fi se adura ati epe, asi le fi bere ohun tia bafe. Ogun yi ti comfirm ju.

2 comments: