All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Wednesday, 7 December 2016

¤AYETA TODAJU¤



Ewe osan wewe, eso afola, eso oju ologbo, ao gun gbogbo re papo mo ose.
Ao waa da eso oju ologbo sinu ose na.
ao maa fiwe.
NB:- Bi eso oju ologbo na se n jabo, beeni ota ibon tiwon bayin siwa yio majabo sile.

7 comments: