All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Wednesday, 7 December 2016

Ogun airi omo bi

Ewe iyalode pupa…ewe mafowokan omomi…ewe akintola pupo…leyin ao wa lo si bi ti igbo ba posi lowo otun ati osi…yi o di ju ja ewe otun pelu owo otun … yi o di ju ja ewe osi pelu owo osi…ao wa fi gun po mo ose… Ale ojo ti oba fi we o gbudo ni kan po pelu oko re.

No comments:

Post a Comment