All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Wednesday, 7 December 2016

OGUN ALAKALA

Ewe sayo, Epo obo, ao gun po Igbin nla kan, ao gun igbin mo, ao yo ikarahun igbin yen ao gun kuna lori olo , ao da sinu eyi ti a gun ninu odo, ao po ose mo ao ko sinu ike funfun kan, idi ose yi ko gbodo kanle. Ao ma we ni gba gbogbo...

4 comments: