All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Friday, 19 August 2016

 ASINA AWON AGBA GIDI.
 ........ORI OLOGBO MEJI TONI IRUN,EWE ORIJIN,EWE AJEOBALE,OWO TUNTUN NLA KAN #1000 OR #500,AOFI OWO YI TELE APE,AOKO ORI OLOGBO SIRAWON NINU APE,AOFI ATARE SI LEGBE,AOWA KO EWE LE LORI AOJO AOLO KUNA AORO SIBI KAN AOMA FI KINIYEN LO LARO KUTU LAITI SORO SI ENIKANKAN......DANWO KIO RI

ISORA /AGBELEPOTA TODAJU GAN..
....ORI AWONRIWON KAN,PATAKO ESIN,ISU OGIRISAKO,ODIDI ATARE KAN,AOJO PAPO AOLO AORO SINU ADO ATO KAN,AOMA BU DIE SOWO PE OHUNRE,EJIOGBE NI IFA RE.....OHUN RE....ORI NI AWONRINWON NI TIFI PE LAIYE,OKO NI AGBE NFI ISU OGIRISAKO SI DI EEMI,KUTAKURA KUTAKURA AIYE NI FI ILE SILO,KI GBOGBO AWON OTA MI,KIWON FIMISILE SAIYE LO,EMI.....OMO.....NI KINREYIN AWON OTA MI....ADUA....AOLA AOMAFI OMI LO...HMMMM......

EYONU ASIRI BIBO 
----epo obo,aogun pepe,aoda sinu ape,aidan pupo aose lelori,odidi atare kan,aojo po aomafi omi aye lo lararo pelu ofore---oni dandan ni taidan3x bokunrin ori owo bobinrin ori owo bomode ori owo bagba ori owo,dandan niki emi----omo---ri owo nlanla loni,ki okunrin ati obinrin ma gbe owo nlanla wa fun emi----omo----.ti oba wuwa alete ejiogbe si die ti afe lo,tabi ki ape ofore nikan si ki asi lo,odaju gan
Ogede wewe pupa, ewe esinsin fun fun, ewe sawerepepe, ewe oyo, ewe rekureku, ao gun papo., ao fi iyo lo papo, ao ro sinu ado ijamo, ao so si enu ona ile.
Ebe agba.
Ewe agbasa ati egbo re , eru mesan, ao gunpo, ao po mo ose dudu, ao ma fi we lararo.  
Ebe agba
Awe ajekobale, odidi igbin kan, ewe ti esisin bale, , ao gunpo mose dudu, ao maa fi we gbogbo ara.
Ebe agba
Ewe ewuro, ose dudu, ori, ao gun po, ao maa fi we.  
Aworo
Egbo orogbo, eru, ako okuta, omidun ogi, ao fi iyo tele inu oru, ao ko okuta ako si, ao ko egbo orogbo le, ao da omi ogi lelori.
Imule Owo
Eran etu, eso ogirisako, ata ijosi iyo, epo, ao se lobe.
Awure owo/OSHOLE OWO
Ori aja gbigbe kan. #100 tuntun ao ki si eti otun. Ao wafi #20. Ao wafi #200 we igbo ao kisi enu ori aja na. Ao wafi ewe sawerepepe su osuka ao gbe ori aja na si. Ao wagbe gbogbo re sinu agbada ao fi  odidi atare kan. Ao jo papo ao mafi oti schinap lo laro laro
Aworo
Ewe ogbo meta, ao gun po mo ose dudu,ao le mo ara amu omi, ao ma po mole lararo
.Awure owo gbigba
Afara oyin, ipe ire, odidi atare kan, ao jo po, ao ro sinu igo, ao ma bu sinu ipara diedie.
Eyonu aye.
Eepo obo, imi ojo, iyere, ao lopo, ao da sinu adin eyan, ao ma fi para.
Apa mowo owo.
Atare aja, korofo tadie pa ku, ao lo ti yoo kuna, ao fi sin orun owo mejeeji yika.

                                Ariran ounje.
                   Irula didi kan, ataare odidi kan, ao jo po, ao fi sin orun owo mejeeji yika

 afaro.
Eku asin ti won pa ju si orita,ikamudu, ileke itun, ifa, abere, ao jo po a wad a sinu lofinda bintu, a wa fi para
lararo.

Eyonu.
Ewe ewuro, ewe omisinmisin, ori, ao gun po mo ose dudu, ao ma fi
we.

Aworo.
Ifun akuko adie, ako alangba 1, ewe sawerepepe, odidi atare kan, aa wa ko gbogbo re sinu akeregbe kekere, a awa da iyo le lori, a wa fi aso funfun di lenu, a wa so ko si enu ona abawole.

Awure ose itaja.
Igo oyin gidi kan, lofinda bintu merin, ori osin, ori ere, ose dudu, awa gunpo, ao ko si inu awo tanganran olomori, ao wa we laso funfun, ao wa ma fiwe lararo.

Osole.
Ipe ire mesan, odidi ejo kan, odidi awo lili kan, padi atare kan, a jopo aa lo kuna, a ma fi foko mu lararo.

Ise anu.
Obi ifin kan, a age si 201, obi pupa kan, a age si 201, eyo atare 201, ao fi omi omu po papo, ao ro sinu ado ijamo kekere, ao fi awo ijimere ran, aa wa ma fisapo.

Awure owo.
Oga aye, tagiri, igbe ewure to bimo re, igbe aguntan to bimu ri . ose dudu 300, ao gun po, ao
ma fiwe lararo:
(gbolohun re) “boro boro lewure su mi re, boro boro laguntan su mi re, ojojumo ni tagiri nka owo tie, aba ti alagemo bada ni orisa oke ngba, mo daba ki won ma mu nla nla wa fun mi loni.

Awure owo.
Egbo iroko, egbo ipon, karagba idi esu, ose dudu, ao gun gbogbo re po, ao ma fi we lararo.,
gbolohun: “ipon loni kan pinre temi fun mi loni, iroko loni afaro.

Awure.
 Ori ikun kan, ori agbigbo(dododo) kan, padi
ataare kan, ao jopo ao ro sinu ado ide.
Lilo re> Ao bu die si owo ao pe ofo re so ao da senu ao fi hot sin
Ofo re> Agbigbo oma kuu eru o (3ce), ikun(remi) loni ki efi owo
owoyin kun owo towa nile(mido), ikun loni ki efikun owo mi
towards ni bank loni....... Adua.
A won tolaye yio gba funwa o
.

 EYONU AWON AGBA TODAJU
----eyin adie ororo 3,aofi tele ape,aoko epo obo lelori,odidi atare kan,ewe anu,ewe orijin,ewe ajeobale,ewe owo,ewe oyo,aojo gbogbo re po,aolo iyo mo,ogbe iyonu ni ifare--OHUN RE---haa!3x,olukibinu olu 3x,osinkibinu osin 3x,obajalaye ki binu oba ajalorun 3x,oba ajalorun ki binu oba ajawole 3x obajawole ki binu oba aja dobiridobiri 3x oba aja dobiridobiri ki binu oba atiledilele 3x otoku ilu ki binu ko iyosile komaje 3x oso ki binu kiwon ko iyo sile kanmaje 3x enikan ki fi oyin senu kotu ito 3x beni enikan ki fi iyo senu ko pose 3x mulobe ni oruko ti ifa npe iyo,yowon ninu gerege ki omode mayonu simi,ki agbalagba ma yonu simi------emi-omo----lati oni lo.eyiti abafe dasinu oyin laote ni ogbe iyonu ooo,aomala lararo

Do it is working perfect

No comments:

Post a Comment