All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Friday, 19 August 2016

Imule (Convenant) with the Elders

IMULE AWON AGBALAGBA KIWON MALE DIWA LOWO-
igbin apinu kan,oga gbigbe kan,eku asin kan,ewe egele,yerepe,ewe kileofimise,ewe ajeobale,opolo gbigbe kan,odidi atare kan,aojo papo aolo kuna,aote ni osa meji,aope OHUN RE--igbin kiise eran taye nje,oga kiise eran apata,bi abamu opolo lodo ti koba jo konko,amansole ni,eyin eleye e gbe mi ju sile,e je kinri aiye temi se,agbe sole ni tewe egele,akopada niti yerepe,aje kan ki gboju koje eku asin,aje kan ki gboju koje oga,aje kan ki gboju kobale igi ajeobale,ki emale ba lemi mo,modi igi ajeobale emi--omo-- tidi ewe kileofimise loni-adua.aomafi epo pupa la lalale.

No comments:

Post a Comment