All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Monday, 24 July 2017

Ogun Airi Omo Bi



Ewe iyalode pupa
ewe mafowokan omomi
ewe akintola pupo…
leyin ao wa lo si bi ti igbo ba posi lowo otun ati osi
yi o di ju ja ewe otun pelu owo otun 
yi o di ju ja ewe osi pelu owo osi
ao wa fi gun po mo ose
… Ale ojo ti oba fi we o gbudo ni kan po pelu oko re.

1 comment: