Ewe ogbo meta, ewe apada
meta, odidi oga kan, omi toromini, Áo jo papo mo ose, ao ko sinu aso funfun, ao
so ko si ibikan ninu ile (house) ti kogbodo kan ile, (ground). T ia abafe lo ao
bu die ninu ose yi ao ko si owo, ao daruko obinrin ti a fe lo fun sinu re, ao
fi we owo mejeji.
OFO RE.... Ogbo loni ki o gbo temi lonni,
apada loni ki o ma le pa oro mi da, aso alaso ni oga ngba, ekun elekun ni
toromini n ji sun, ekun mi ni ki lagbaja ma sun loni o . ODAJU confirm
Baba Ekale o ewe Yi o make o Amin.bawo ni ase malo ise Yi ejo Tori olorun e salaye re funmi
ReplyDeleteBaba ejowo mo ni lo Iran lowo yin Lori omo birin kan
ReplyDeleteCall this number 08083178398
DeleteO7030580469
DeleteBaba ki ni jẹ́ omi toromini
ReplyDeleteEdakun kin lon je omi toromini
ReplyDeleteGood evening sir thank u very much hope dat it dose not have side effects
ReplyDeleteEnter your comment...baba se o legit
ReplyDeleteEdakun nibo lati leri omi toromini naa
ReplyDeleteBaba ewore
ReplyDeletePlease anyone who knows what omi toromini is should tell us
ReplyDeleteThanks 👍
ReplyDeleteKi lo je Omo toromini
ReplyDeleteIs 🐹
DeleteThank sir
DeleteI need ogun OWO todaju ati ogun eresisa todaju
ReplyDeleteIga tutu abi gbigbe sir
ReplyDeleteOga tutu abi gbigbe sir
ReplyDeletePlease I need confirm Amudo that I can use to talk to a girl
ReplyDeleteI need something here
ReplyDelete