All About Eji-Ogbemi Blogs and Post

Tuesday, 8 November 2016

OGUN AMUDO­­



Ewe ogbo meta, ewe apada meta, odidi oga kan, omi toromini, Áo jo papo mo ose, ao ko sinu aso funfun, ao so ko si ibikan ninu ile (house) ti kogbodo kan ile, (ground). T ia abafe lo ao bu die ninu ose yi ao ko si owo, ao daruko obinrin ti a fe lo fun sinu re, ao fi we owo mejeji.
OFO RE.... Ogbo loni ki o gbo temi lonni, apada loni ki o ma le pa oro mi da, aso alaso ni oga ngba, ekun elekun ni toromini n ji sun, ekun mi ni ki lagbaja ma sun loni o . ODAJU confirm

20 comments:

  1. Baba Ekale o ewe Yi o make o Amin.bawo ni ase malo ise Yi ejo Tori olorun e salaye re funmi

    ReplyDelete
  2. Baba ejowo mo ni lo Iran lowo yin Lori omo birin kan

    ReplyDelete
  3. Baba ki ni jẹ́ omi toromini

    ReplyDelete
  4. Good evening sir thank u very much hope dat it dose not have side effects

    ReplyDelete
  5. Enter your comment...baba se o legit

    ReplyDelete
  6. Edakun nibo lati leri omi toromini naa

    ReplyDelete
  7. Please anyone who knows what omi toromini is should tell us

    ReplyDelete
  8. Thanks 👍

    ReplyDelete
  9. Ki lo je Omo toromini

    ReplyDelete
  10. I need ogun OWO todaju ati ogun eresisa todaju

    ReplyDelete
  11. Iga tutu abi gbigbe sir

    ReplyDelete
  12. Oga tutu abi gbigbe sir

    ReplyDelete
  13. Please I need confirm Amudo that I can use to talk to a girl

    ReplyDelete
  14. I need something here

    ReplyDelete